01/09/2026
AGBO OYUN IJU EYIKEYI (FIBROID)
Oyun IJU je Arun kan Tino ma ndamu Obinrin nikan ti o si jepe Oni Awon Ohun ti o ma nfa Arun yi.
Oniruru Aisan iju (Fibroid) yi ni o wa.
Opo Awon Obinrin Ti won ni Ipenija yi ni won ti lo Oniruru Ogun Sugbon sibe sibe kosi Iyato Rara, bi Eniyan base ndagba si ni IJU (fibroid) yi na ma ndagba si.
Ninu Awon iwadi Imo Ijinle, won kofibe ri pato aridaju Ohun ti o le ma fa Aisan yi, sugbon Ninu Awon Ohun ti I saba ma nfa ju ni:
β’Arun Ibalopo Olojo Pipe (Long term STI)
β’Oyun Sise (Abortion)
β’Ifeto somobibi Olojo pipe
(Long term Family planing)
β’Apoju Ara sisan
β’Riri nkan OSU bi 11/12 yr (Early Period)
Eyi Awon Apere
β’Apoju Nkan osu sise (Heavy Meanstrual Bleeding)
β’Ogoro Eyin Riro (Lower back Pain)
β’Isale Inu rirun (Pelvic Pressure)
β’Ito Apoju (Frequent Urination)
β’Irora lakoko Ibalopo (Pain during s*x)
β’Aikomari Oyun ni (Unable to Conceive)
Ti o ba gbiyanju ohun ti mofe salaye re yi odamiloju pe wamadupe fun olohun oba ni.
Ikan TI a mawa
β’Ewe Iyeye Tutu
β’Epo igi Amunyan
β’Bara
β’Kahun Bulala
β’Iyo Isebe
β’Omidun Agbado
BI AO SESE
Ki a RI daju wipe adi Ewe Iyeye si ona meje,
Ao fi Omi fo Gbogbo Awon Eronja yi nu ki o mo dada, ao ko Gbogbo Awon Eronja yi tele Inu Oru, ao wa ge bara yi Kekeke ao kole Ori re, ao fi Omidun yi se ki o jina dada fun bi Ogbon (45min) iseju Tabi ju belo.
LILO RE
Gass kan ni owuro ati Ale.
Ki a lo Ogun yi fun OSU meta gbako.
Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na.
Lati tunbo RI ekunrere Lori bi a se nlo Ewe Ati Egbo Awon Babanla wa,
Gbogbo wa akonifi Aisan Logba oo ππΏ
remedies
Iwo na Bami Comment, like, and share re fun Anfani Awon Elomiran!
β
βMogba ladura pe Gbogbo wa pata so ni FI asan logba lase
Eledumare
β
βFun Ibere Tabi Ohun Miran Tabi ofe ki abo se kia gbe ranse si o
βWhatssap :- 09133275017
β08051996013
FOR MORE QUESTIONS ASK ππ
This is YEYE ((Many Mother)) AGBOMOLA TRADOMEDICAL FOR ALL Native things, what do you want me to do for you? about your problem mention your problem I will tell you what to do in a Native way
if you want to discuss with me putting your message down or WhatsApp,, call me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about your problem.to no what to do this my WhatsApp number 09133275017 08051996013 or
My Link π
https://chat.whatsapp.com/BUV8jWvpNMMJPeUVHrwrZ6
me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017
AYEWO FUN GBOGBO IWO TI OBAFESE IWADI LODOMI AYEWO ( ) DETAILS TO SEND YOUR FULL NAME
SE IWADI AYEWO ORO IGBESI AIYE RE IF YOU ARE READY MESSAGE ME ON WHAT'S APP OR CALL ME