19/07/2026
BI OTA BATI POJU FUN E LODAN BACK TO SENDER WO
Iṣẹ́ yìí lágbára gan-an láti dá gbogbo aburú padà sí orí ẹni tó bá ń pète ibi sí ẹ. Bí ọ̀tá rẹ bá tó ẹgbẹ̀rún, agbára Ọlọ́run yó ò ṣẹ́gun wọn ọ̀kọ̀ọ̀kan bí wọn kò bá padà lẹ́yìn rẹ. Ìkìlọ̀: Tí ọwọ́ rẹ kò bá mọ́, tàbí tí o bá ń pète ibi sí ọmọnìyàn bíi tìẹ, má ṣe iṣẹ́ yìí rárá nítorí ó gbóná gan-an.
ti o ba fe ko sise fun o koko coment ko de share re tori fun afani awon elomi na ni
Omi (Any quantity of water) Iyo (Salt) - Ẹ̀kún ọwọ́ kan * Da iyọ̀ náà sínú omi rẹ.
* Ka Saamu 51 àti Saamu 109 sínú omi náà.
Muslim ka kuliahusu mejeji mokanla- mokanla
* Lẹ́yìn náà, gba àdúrà ase (declaration) yìí sí i: "Ẹnikẹ́ni tí obìnrin bí, tó ń mu omi, tó ń jẹ iyọ̀, ṣùgbọ́n tó ń lépa ayé mi lọ́nà kan tàbí òmíràn, láti òní lọ, ohun tí wọ́n rò tàbí tí wọ́n gbèrò tàbí tí wọ́n ti ṣe sí mi, kí ó padà sí orí wọn ní ìlọ́po mẹ́rin."
BI O SE MAA LO O
* Tẹ àhọ́n rẹ bọ inú omi náà, kí o sì gbé omi díẹ̀ tí o tọ́ náà mì.
* Lọ da gbogbo omi iyọ̀ yòókù síta gbangba (outside your house).
* Má ṣe ṣe kàyéfì bí àwọn kan kò bá kí ẹ mọ́ tàbí bí o bá gbọ́ ìròyìn burúkú nípa ẹni tó ń dẹmọ fún ẹ; máa bá ayé rẹ lọ nínú ìfọ̀kànbalẹ̀.
Gbogbo ọfà tàbí aburú ti won gbe ti pada sori won niyen, Lora obi pupa lafise saara pelu 200 naira leyin tebafi owo naa nura tan yio bawa Lara mu...