Itoju Iwosan Arun Ara

Itoju Iwosan Arun Ara FOR PEOPLE WHO NEED PRAYER DELIVER FROM BONGADE, FOR YOUR BUSSINESS FOR YOUR MATRIMONY HOME.

10/07/2026
23/01/2026

LATI DARAPO MO EGBE ITOJU ATI IWOSAN ARA LORI WHATSAPP FI NUMBER REE SILE

10/01/2026

ASIRI TI AFI NBO LOWO OGUN AYE (BO***GE)
Nje owa ninu ide, abi aye re wa loju kan,airije, ejowo eje kia gbiyanju asiri yii wo pelu ogo olorun ao ri iyi pada lesekese.

ISENARE:-aowa
Agbon eyokan pere (coconut 1)
ao lora agbon yii funra wa ni,ako gbodo ran eniyan tabi toro re, ao ju agbon yii sile ninu ile fun ojo meta (3days) ao ma fi ese gba lo gba bo ninu ile,leyin ojo keta ao gbadura si agbon yii dada gbogbo erongba wa patapata Lao so si agbon yii, ao se gbogbo eleyii kia to soro si enikeni ni aro nio, ao wa mu agbon yii losi orita meta tojinna die sibi tia ngbe,ao lo fo agbon yii mole pelu gbolohun pe bi mose fo agbon yii gbogbo isoro aye mi ni m**o danu,ao wa pada sile.pelu ogo olorun iroyin ayo Lao ma gbo.. ema fo agbon yii sinu ile ooo,ati pe ibi ti a ba fo agbon yii si ako gbodo gba ibe koja ni ojo na mo
Otun di ojo keji

Address

IREMO Road STREET ILE IFE
Ile-Ife

Telephone

+2349055064510

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itoju Iwosan Arun Ara posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share