Dr. Nohu herbal

  • Home
  • Dr. Nohu herbal

Dr. Nohu herbal specialist on prostate enlargement/UTI/STDs and spiritual problems

Fun iwaosanIba gbigbona (high fever)Iba oni gbigbon ( malaria)Ara riro ( body pains)Ao awon nkan elo yiEwe Isin (ackee l...
04/06/2026

Fun iwaosan
Iba gbigbona (high fever)
Iba oni gbigbon ( malaria)
Ara riro ( body pains)

Ao awon nkan elo yi
Ewe Isin (ackee leaves)
Osan aipon (unripe orange)
Onaga (pineapple)
Fun iwaosan

Ao wa ewe isin tio po die, ao sinnu ti o mon dada, Ao da sinnu koko Kan pelu osan aipon ati onaga, Ao se ti yio jinna dada
Lilo re fun agbalagba cup kan laro ati ni Ale
Lilo re fun omode ilaji cup laro ati ni ale

Fun ibere 08022633112
Gbiyanju Lati mon se agbo yi odara pupo lati fi dena iba ( fever/malaria) ati ara riro (body pains) adua wa yio gba

30/05/2026

Anfani ogi oka baba

Fun iwosan *Ibalopo (erectile dysfunction)*Itoju igbe gburu ati ebi ( hermoroid)*Agbara lori ibimon ( labour  induction)...
11/05/2026

Fun iwosan
*Ibalopo (erectile dysfunction)
*Itoju igbe gburu ati ebi ( hermoroid)
*Agbara lori ibimon ( labour induction)
*Idinku irora (athrites)

Eba mi wa awon ewe yi
Ewe iyeye(hogplum leaves) ati Ewe Elu (philenoptera cyanescens)
Gbiyaju kose ishe yi kowa dupe fun olohun oba to da ewe ati egbo
Ao wa ewe iyeye (hogplum leave) tio po die ati ewe elu (philenoptera cyanescens)
Ao se ti yio jinna dada
Lilo re ilaji cup laro ati Ale. Adua wa yio gba
Fun ibere 08022633112

Fun iwosan airi omobi (infertility)Ito sugar (diabetes)Ipake (hernia)Kokoro oju ara (ge***al infections)Epakun (curcuili...
08/05/2026

Fun iwosan airi omobi (infertility)
Ito sugar (diabetes)
Ipake (hernia)
Kokoro oju ara (ge***al infections)
Epakun (curcuiligo pilosa)
Ewe ewuro (bitter leaves)
Ao wa ewe ewuro
Ati epakun
Ao wa epakun ti yio kun owo kan, ao bo epo ara re ti ao si fonu dada pelu omi to ba mo, besi ni ao wa ewe Ewuro die, ao sinu dada ninu omi tomo.
Ao da gbogbo e sinu ikoko kan aose jinna
Ilaji cup laro ati ale ni lilo e.
Ao ni fi aisan logba
Fun ibere ati alaye 08022633112

OGUN IWOSAN NI ILANA IBILE ORO IYANJU ATI AKIYESI PATAKIOgun iwosan niti ilana ibile odara pupo tenuko, papajulo tio tun...
30/04/2026

OGUN IWOSAN NI ILANA IBILE
ORO IYANJU ATI AKIYESI PATAKI
Ogun iwosan niti ilana ibile odara pupo tenuko, papajulo tio tun fi tolohun siwaju.
Ogun ibile osini odiwon (dosage) opo ogun ibile la nfi odiwon gasi kan lo laro ati ni ale yio sise ti cup nla yio se amon cup nlanla kose fi lo ogun yio gba odi lara (overdose) .
Kio lo ogun laro osan ati ni ale koburu nibe iyara ni oje fun iwosan.
Imoran fun gbogbo wa ni wipe ki aisan to pe lara ki a tete jade wa iwosan
Eniti o lo ogorun Odun laye (100 years) owu olohun be tio si wu eniyan na be. Amon bawo ni osele to ju ara re si?
Fun ibere 08022633112

Bara (bitter melon)Nje iwo mope Bara (bitter melon) aman fi se awon iwosan bi Airomo bi (infertility)Ara rito (body pain...
23/04/2026

Bara (bitter melon)
Nje iwo mope Bara (bitter melon) aman fi se awon iwosan bi
Airomo bi (infertility)
Ara rito (body pain)
Eje kiki (cloth blood)
ati bebelo


Fun eku rere alaye ati ibere, epe si ori ago yi abi ki ete ate Jise siwa lori WhatsApp 08022633112

Koro agbalumo ( Star apple seed).* Fun itoju Aisan jejere omun (Breast cancer)Olohun oba se eda orisirisi eso (fruit) ti...
14/04/2026

Koro agbalumo ( Star apple seed).

* Fun itoju Aisan jejere omun (Breast cancer)

Olohun oba se eda orisirisi eso (fruit) ti enu je, to sin se anfani fun ara gegebi iwosan ara.

Lati lefi mon bi ao se lo koro Agbalumo lati fi toju aisan jejere inu omun (breast cancer) ati se alaye re sinu comment.

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo🙏
Fun ibere 08022633112

Iwulo koro Agbalumo (African star apple seed)* Fun iwosan Oju ara obinrin toba fe  (loosed viginal)* Fun iwosan omun obi...
07/03/2026

Iwulo koro Agbalumo (African star apple seed)
* Fun iwosan Oju ara obinrin toba fe (loosed viginal)
* Fun iwosan omun obirin to ba wale ( sagged breast)
* Fun iwosan inu kikan nkan osu ( menstrual cramps)

Koro Agbalumo (Africa star apple seed)

Gbogbo Ohun ti Oluwa da, daradara ni, Olohun oba ko sadede seda Ewe Ati Egbo si Ori oke Yerupe, bi kiise fun Anfani Ati Lilo awa Eda.

Ao wa koro Agbalumo ti yo po dada, ao pa ti ao si yo tinu re jade, leyin re ni ao gun ti yio kunna dada, ao sa sibi ti ko si orun.

Lilo re idaji sibi omode ni ale.
Alaye eleyi wa fun eni ti oma ni inu kikan koto see nkan osun

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo🙏
Fun ibere 08022633112

FUN IWOSAN OYU NINI (INFERTILITY)LILO EWE ELU Opolo Loti lo Oniruru Ogun Sugbon ti won koni Oyun aro di Ale riOhun ti o ...
31/01/2026

FUN IWOSAN OYU NINI (INFERTILITY)
LILO EWE ELU

Opolo Loti lo Oniruru Ogun Sugbon ti won koni Oyun aro di Ale ri

Ohun ti o le fa ki Eda ki o ma tete RI OYUN ni po gaan sugbon Eyikeyi ti o baje nibe, ewe yi kapare gaan ni

BI AO SESE
Ao lo wa EWE yi ni Tutu, pelu Ewe Etiponola Tutu ao SE papo ni agbo, ki o jina dada fun bi Ogbon iseju,

Lilo re
Mimu ni Idaji glass cup ni Emeji lojumo

Mogba ladura pe, Gbogbo Agan Tiwon nwo Oju Eledumare fun omo, ole AYO a*o Ninu onikaluku Lati Oni yi lo.

Iwo na bami share re fun Anfani Awon Elomiran.
Gbogbo Ohun ti Oluwa da, daradara ni, Olohun oba ko sadede seda Ewe Ati Egbo si Ori oke Yerupe, bi kiise fun Anfani Ati Lilo awa Eda.
Fun iwadi ati ibere 08022633112

Address

Ilorin

031

Telephone

+2348022633112

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Dr. Nohu herbal posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Dr. Nohu herbal:

  • Want your business to be the top-listed Health & Beauty Business?

Share