09/07/2025
OKUN JANKARIWO (WEB)
TONKONI LOJU NI GBOGBO IGBA
=======================
Oga Gbigbe 1
Isasun Kekere Tuntun
Odidi Atare 1
JANKARIWO kikoni loju je Awon Apere Ami (Sign) ti kodara rara, Bee Aye a si ma fi deni looto,
Awon Alaimokan miran a masope, Owu Alantakun lasan ni pe kolese ohun kohun fun ni,Pele o,mo ki o ku Aimokan ti nba o ja.
JANKARIWO, kole di igi, beeni kole di nkankan, sugbon ti Aye bafi de eniyan, t**i Ayeraye, Eda o ni bo ninu re
Ewu (Risk) ti o wa ninu ki JANKARIWO maakoni loju ni gbogbo igba po Debi pe, kiijeki oro aye Eda o ni ojutu ni, Bakaana Amamuni La awon Oniruru Ala Buruku, Eyi a situn ma fa Ifaseyin funni Ninu Irin Ajo Aye eni.
Ti o ba gbiyanju Ise yi, pelu ogo olohun oba JANKARIWO na o di ohun ti koni koniloju mo.
BI AOSESE ISE NA
=============
Ao lo wa oga gbigbe (Carmelion) ti o pe eyokan, ao wa lofi ko Gbogbo JANKARIWO ti o ba wa ni ara ile ti oga na o ni han ma rara, ao gbe sinu Ape ijogun tuntun, ao di Odidi Atare kan si legbe,ao jo Gbogbo re papo, ao lo ti o kunna dada leyin ti o ti jo tan, Ao pin Ebu na si ona meji.
LILO RE
Ao po okan mo ose dudu,ao mafi we ni owuro ati Ale,ao si ma fi Ekeji fo Eko Tutu mu ni Owuro ati Ale bakana.
Okun ti Omo Araye fi ndeni ti Oro Aye Eni kiifi ni Ojutu, Mobe Olohun oba, ki won o mafi de wa Tebi T'ara wa oo๐๐๐
Fun Ibere Tabi Ohunkohun
ASHABI AGBOMOLA
(IYA-EWE)
08127371923