24/08/2026
OGUN KOKO OMU/SOMU RORO
Koko Oyan je Aisan ti o ma ndamu Obinrin, ti Opolopo Obinrin siti lo orisirisi Ogun Sugbon ti ko lo, ti o ba gbiyanju ohun ti mofe salaye re yi, Iwo na o mo wipe iwosan nbe Ninu ewe Ati Egbo.
Ao lo ja Ewe yi Oojo, eyoka , ao wa fi ra Ina dada ki o le ba furo dada, ao wa pelu Obuoyoto.
Ao ma fi pa Dede Ibi ti Koko na Bawa Nibi OYAN wa.
Ki a mase be lojojumo.
Nigbati ao bafi lo lera lera, Koko na yi o bere sini ma yo diedie ni.
Iwo na Bawa share re ki o so like re fun Anfani Elomiran na.
Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo oo 🙏🏿