Captain Alternative Therapy

  • Home
  • Captain Alternative Therapy

Captain Alternative Therapy To see to the improvement of health and well-being of mankind through the use of local herbs.

Cure for hepatitis B...dm for more info🌿🌿
04/02/2026

Cure for hepatitis B...dm for more info🌿🌿

26/01/2026

Say goodbye to 2 minutes of premature ej*******on

To see to the improvement of health and well-being of mankind through the use of local herbs.

29/12/2025

FOR Jaundice
GET UNRIPE PAWPAW WASHED AND CUT INTO SMALL SIZE AND SOAK WITH OMI DUN ( PAP WATER) FOR TWO DAYS AND BE GIVEN THE BABY tea spoon full morning and night.
Please share and comment.

Adalu fun opo gigun (Mixture for chronic pile)
26/12/2025

Adalu fun opo gigun (Mixture for chronic pile)

25/12/2025

Àtúnṣe Àìsàn Sémìí-sémìí (Asthma)

Ohun tí a nílò: akọ alángbá kan(male lizard)

Báwo ni a ṣe lè ṣe é?( What to do?)

Fọ alangba naa, lẹhinna ge e si awọn ege (mẹta tabi mẹrin). Lẹ́yìn náà, se é fún wákàtí kan, lẹ́yìn náà, yọ aláǹgbá náà kúrò nínú omi. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí omi náà tutù dáad , lẹ́yìn náà, fi bí ṣíbí oyin márùn-ún kún un kí o sì da pọ̀. Mu ni gbogbo oru lẹhin ti o ba jẹun

10/12/2025

Fun iwosan eti didun
Alubosa ayu
Bo epo ara alubosa naa ki o fi owo mejeji raa papo ki o wa fi sinu eti naa fun Ogun iseju ojo meta aro ati ale

06/12/2025

For sore throat
Soak one full of grand alligator pepper in gin and be taking sort morning and night three days
And thank me later

To see to the improvement of health and well-being of mankind through the use of local herbs.

05/12/2025

Fun JediJedi
A o lo wa ewe lapa pupa
A o gbo ewe naa a ko ni fi omi SI o, omi to ba jade Lara ewe na la ma fi fo eko mu.

10/09/2025

For any back and waist pain in men, get one big bitter lemon and honey and mix together
Preparation:
Place the bitter lemon on the fire and extract the water and mix with honey.
Or call me for more information on
09020925596

07/12/2024

To cure malaria instantly, get
Ewe afefe
Irenu ewe ako ibepe
Epoo amuje
Eepo awopa
A o se gbogbo eroja yi papo fun ogbon iseju
Leyin ogbon iseju odi mimu laaro ati aale pelu 50 ml cup

Address

Ogijo

Telephone

+2349020925596

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Captain Alternative Therapy posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Captain Alternative Therapy:

Shortcuts

  • Want your business to be the top-listed Health & Beauty Business?

Share