Baba keugbemi

Baba keugbemi I'm cleric kewugbemi deal with spiritual stuff

12/02/2023

ISE TI GBOGBO YI PARIWO FUN . OHUN MOTI FI KALE YI OO ...... fun opolopo eyin teni eti na owo tan Fi se odun , abi Iwo nilo owo kiakia larin ose kan si ose keji lati fi ri owo , lo dan ise Yi wo , ise Yi Yara pupo gidi gan lati Fi ri owo lonakona, larin ose kan si ikeji, kosi na wa ni owo pupo rara.....sungbon wa gbo mi loni oo ranti ojo ti yo ku Iwo ati e le da re ninu sare kosi ranti ese mefa ..Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ekun oJo ale ..ma dawo duro ki o ma ba wa aye asan, iye awon eniyan ti o ti dide lati ipase mi lati ori Facebook koni oun ka rara ki olorun o san emi na nii esan rere ... Ise na re... Ao wa eyin Agric meji pere , moti so fun o Koni sise fun o ti o ba comment ki o de share re oti di ase , tori fun afani elo mi na ...ao wa Fi ewe iyalode pupa mejo tele isasun tuntun, ao wa ko eyin Agric meji yen sinu re , ao tun da ewe iyalode pupa mejo mi bo mole , ao wa de pa, to ba jina tan ,ao so si ile le, ao se adura owo Sii wipe ka ri owo lonakona ni kiakia, ao wa je , Iwo kan lo dan wo, odaju lati fi tete ri owo lonakona , Koda mo Fi owo soya le Lori papa....Mo tun so bayi tete lo darapo Mon group mi Lori Facebook YARA ASIRI ANU , tori to ba ya mi o Ni gba enikeni wole Mon oo
09157750288

Dupe kio bale je fun e
Fun Iwo tobanifesi alajo ojojumo
Ifayemi babatunde ni oruko temi
ogun tioje ewe re loku kan
Inu wallet dudu ni ama pari iseyi si
20000 naira pere deni oun muwa ni ojojumo , ti Abafe ba iyawo wa ni ao jo sepo, a gbodo yo wallet yi kuro ninu apo wa
Inu 20000 toba de ti muwa ni ojojumo a gbodo mafi 1000 naira fun oni bara kan ninu eyo Toba gbewa lojojumo
Ki iseyi lema mu 20000 yi wa PE ni ojojumo
IWO TOBA NIFESI TOSE TAN Fun anfani wa fue Lati PE NUMBER MI
09042442775

07/02/2023

LATI OWO alfa harbefe

OGUN TIOJE EWE RE LOKU KAN Asiri owo tanfiri 200,000 Larin Ojokan ojo taba lo nani oma gbe 200,000 wa ,gbobo eyin scammer 419 te message mi Lori WhatsApp wipe kiye sepe Mon tin ba ti fe post ise gbogbo yi ni aye yi yo baje ti esan yosi ke Lori yi ....., inu mi dun wipe emi gan lo ise yi mode ri ise re , eni toti ni oruko kotun gbodo ma wa oriki kakiri Mon , pupo eniyan lo Mon mi ninu group yi tori idi eyi ti mio ba ti dan ise wo kin De ri pe o confirm mi ko ni post rara , ise to daju ni ise yi emi yato si gbogbo awon to mo post ise, ti pupo awon to wa ninu group yi si Mon mi daju

Ise na re oo_ Ao wa isasun tuntun kan ao fi ewe abamoda tele ikoko , ao fi eyin ibile kan le, ao wa tun fi ewe abamoda kan bo ao gbe kanna ti eyin yi bati jinna , ao so sori osuka sugbon osuka na a*o funfun lo gbodo je oo Ao wa pe ohun re si bayi

Ofore_ _ abamoda kan kin da aba tie komase 3x , aba ti alagemon ba da ni orisa oke ngba 3x , aba ti emi lagbaja omo lagbaja ba da loni kose ki emi lagbaja omo lagbaja ri 100,000 ki ile oniyi tosu, ao wa je ao mun oti le Lori nigba taba ti je ise na tan

IKILO*** ise yi koni sise fun eni tiko ba share re kode comment ase ni , elo mi wa to je gbese tosi je wipe to ba ri 200,000 yo si San gbese re tori na share re tori elomi yo dara fun wa o ise yii wa fun tita call 09042442775

ASIRI OGUN ASEGBE AFORAN ( TO SCATTER CASE IN THE COURT OR ANYWHERE ) TESTED AND CONFIRM ATI Jss1 Secondary school Nimo ...
07/02/2023

ASIRI OGUN ASEGBE AFORAN ( TO SCATTER CASE IN THE COURT OR ANYWHERE ) TESTED AND CONFIRM

ATI Jss1 Secondary school Nimo Ti nlo ASEGBE Yii Kona Mii Ni #5 Kobo Rii.
Tiwon bafe Le omo nii SCHOOL TO BA LO IFA YII WON KO NI LE..

Ounje Bi IDAN... ASEGBE AFORAN (TO scatter CASE)
Eo BU EERU INA (ASHES) Sii Atelewo OSI ao te IFA Ejiogbe sii • • Ao pe Gbolohun si
• •
• •
• •
Gbolohun Re..👇

Eeru ni Oun yo di Oke moni ko le di oke, Eeru ni oun yo di omi Moni kole di omi,
Eeru ni oun yo di Ile moni kole di ile, ojo tii EERU Danwo ojo un nani Abare tan, Ki Aba lagbaja omo lagbaja dii Asan Lori emi lagbaja omo lagbaja Loni...

LILO RE 👇

Ao Fi Enu Fe Eeru yii Danu lesekese Tori ASIRI awon agba atijo ni Tosi daju pupo

Dupe kio bale je fun e

09042442775

Ado ijogbon ☠️☠️☠️☠️☠️

ASIRI IFA TIA FINGBA ISE CONTRACT OLOWO NLA TODAMILOJU:  ao lora opolo gbigbe 3,oga gbigbe 3,adaripon aye kan,oromo adie...
06/12/2022

ASIRI IFA TIA FINGBA ISE CONTRACT OLOWO NLA TODAMILOJU: ao lora opolo gbigbe 3,oga gbigbe 3,adaripon aye kan,oromo adie aye kan,eso werenjeje ilaji agolo,okun sokoto tia sinlo,tagiri kan tolaje lara dada,ao kowon sinu ape,ao wasa tagiri yen si wewe lelori pelu okun sokoto yen,ao jopo,ao lo kuna,ao pin sona mefa,ao mafi peak milk olomi kokan lo lalale fun ojo mefefa pelu adura,AKIYESI: wonle gbe contracts ti akomo nipa re wa agbodo gba oo,ki awa eniti omaran wa lowo nipa re nio,odaju biku, Dupe kio leje fun e,elomi yio mu biro yio mako ise wa kale laidupe, ,hmmm mio bere owo lowo re kinto yonda asiri yi fun e,mo tunfi asiko temi sile latifi ise tayin loore,iwo na fi asiko die tofika fi dupe lowo OLORUN, bibeko ise yi konije fun e rara,mio femo bi ose gbona to ninu aye,koda kio je Egbeji,eranti wipe Okunrin tonsun rara fun okunrin egbe re Ako ise lonse !!! FUN IWO TOBAFE RA OSE ERO AMUBO ORE TI GBOGBO OGUN PROMISE&FAIL YIO FISE,OWA NLE BAIBAI,PEMI SORI ERO IBANISORO YI: 09042442775 Massage me or call

AGADAGODOAgadagodo pupa kan(red padlock)igi to o ku si Ori inaro ao Fi ada ge die larare ope to ko si Ori inaro ao Fi ad...
24/10/2022

AGADAGODO

Agadagodo pupa kan(red padlock)igi to o ku si Ori inaro ao Fi ada ge die larare ope to ko si Ori inaro ao Fi ada ge die larare, panumon abo mesan panumon abefe mesan pelu owu dudu ati funfun

Sisere....
Ao to gbogbo eroja na mon agadagodo na ao fi owu dudu ati funfun di dada ao ti Omo kokoro na bo ni idi

Lilore
Gbogbo igba ti a ba fe Lo ti a ba ti so aniyan wa si tan ao ti pa,ti a ba tun Fe se n kan mi pelu re ao si ao tun so aniyan wa si ao tun ti pa

Ofore

Igi toku kin roju ruwe /3*
Ope toku kin roju yo ogomon/3*
Panomon abo kin ba abo wijo/3*
Panumon abefe kin ba abefe fohun/3*
Owu dudu,owu funfun kin jarawon niyan
Kori be kose be

IRE OO
Fun ibeere massage me Lori WhatsApp 09042442775

DM ASAP
18/10/2022

DM ASAP

Awon tira ti ose lo aye re re oooo
18/10/2022

Awon tira ti ose lo aye re re oooo

Address

Osogbo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Baba keugbemi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share