Alafia looro iwosan lagba herbal misture

Alafia looro iwosan lagba herbal misture graduate of university of ilorin

02/07/2025

graduate of university of ilorin

02/07/2025

Huuummm opo eniyan ni aisan ti ran losi oorun aremabo tosi jewipe aikiyesi ara ni ofaa opolopo ati afojudi, paapa julo # # # fun eni toba gbagbo lododo ni Mon ba soro, mo oluwa toni Emin mi lodo bura se egba wipe aisan jedijedi yara pa eeyan bee sini aisan iba jefun jedo ti anpeni typhord naa yara pupo Lati ran ni, ni oorun aaremabo ni tori momon oopo eniyan ti awon aisan yi ti ranlosi oorun aare mabo,
EJE KI ALODAN AGBO YIWO FUN ENI TI ONI AISAN IBA JEFUN JEDO TIYPORD TODAJU GIDI GAN TI MOTI FI OPOLOPO ENIYAN SAN DAADA, SUGBON OO OLOHUN LOWA NI DIDAJU RE OO.

Ao lo wa ewe laali ti won man tosi owo, pupo re ni ao wa, ao ewe ibepe eyikeyi iye ti oba wuwa, ao lora eepo igi Apaa ni awon alagbo omo, fun eniti oba Damon ale lopa fun rawa, ao fi ata ile si ti amon si ginger tutu iye ti oba wuwa, ao wa fi omi dun se, omi ogi (pap water) ao se ti yoo jina daada ao ma fi se omi mun ni igba ki gba, (Akiyesi pataki) Ti omi bati fe tan ni ori re ao tun fi omi miran si, Agbo yi tun sise fun eni ti oba ni (infection ) olojo pipe lara odaju gidigan Ase olohun oba wa larare.

graduate of university of ilorin

Address

No. 15 Owode Street Igbona Oshogbo
Osogbo
234

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Alafia looro iwosan lagba herbal misture posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share