Ogun Ibile Awogbeminiyi

Ogun Ibile Awogbeminiyi Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ogun Ibile Awogbeminiyi, Odo fun fun area ikoyi, Ikire.

Ayeta to confirm08036608468
24/12/2023

Ayeta to confirm
08036608468

06/10/2023

Fun awon ti won ta Ile house 🏠
ATI awo to n ta Ile land
Agent



Ewe ina tutu
Ewe esese tutu
Ewe aaragba tutu
Ewe oloyun tutu
Okuta ako
OSe dudu




Ao gun gbogbo awon ewe yen po Mon OSe dudu ao ko sinu igba olomori



How To Use it

Ao gbe Ile nibi Ile tabi Ile ti a Fe ta
Ao gbe okuta ako sinu ina ti yio gbona girigiri
Ao gbe sinu Ile ti agbe yen
Ao bu die ninu OSe yen
Ao fi sii atelewo wa
Ao ma fi omi tutu fo OSe yen le ori okuta gbigbona pelu gbolohun yii
Leyin gbolohun yii
Ao da yepe boo mole
Tested and confirmed

Gbolohun
Kankan ni ewe inajo
Warawara ni omode toko esisi bo
Ile ogba ona ogba ni Se ewe aaragba
Omi gbigbona kii Duro lenu kope o
Eyin to laye elo tii eni ti yio ra Ile yi wa bayi bayi ewe oloyun kii kohun obarisa
Eyin to laye ewa gbogun enu mi
Ao Se adura sii
Ao wa yepe boo mole
Osanyingbemi
08036608468

16/09/2023

OSe fun eni to n wa oko ISE tabi Aya
Pelu onise owo onisegun nurse ATI beebe lo
Ewe agogo igun
Ewe bonbo awodi
Itun
IFA
Abeere
Ori Oka tutu
OSe dudu

Ao gun gbogbo re po ao ma fi we

Gbolohun
Oro to n dun Babalawo lo n dun IFA
Eyi to n dun orisa lo n dun Osanyin
Oro ISE /oko/ iyawo lo n dun Emi l Omo L
Itun lo ni ki e fi ISE / oko /Aya rere olowo nla tun mi Se
IFA lo ni ki e fi _ - _ _ rere olowo nla fami mora
Abeere Loni ki e fi _ - _ rere olowo nla beere mi
Agogo igun ye igun afi fun igun ISE _ - _ to yemi eyin to laye efi funmi
Bonbo awodi ye awodi afi fun awodi ___ - _ toyemi ni rere eyin to laye efi funmi
Ibi ti Oka ba basi ni ounje ti e ti wa n ba ki Omo araye wa ma fi ISE wami wa sii ayemi
Adura
Osanyingbemi
Awogbeminiyi
08036608468

16/09/2023

Ki ebo fin ki ebo da
Ki ebo de ode orun

16/09/2023

Address

Odo Fun Fun Area Ikoyi
Ikire

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ogun Ibile Awogbeminiyi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share