Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani

  • Home
  • Nigeria
  • Ilorin
  • Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani

Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani Onikurani

03/06/2026

Repost........

Moti fi iseyin kale tipe sugbon opolopo awon eniyan ni won dupe lorire lojeki n repost komaje anfani fun gbogbo eni tiko batise iseyin..
IFERAN TABI OWO (MONEY)%

Mofi iseyin kale fun awon tiwon private chat me ko maje anfani fun gbogbo eyin agbalagba...ona pupo lale gba lo iseyin....ale lo fun iferan obinrin tabi iferan okunrin tabi ki oga ni ife omo ise...tabi a need owo...

A o Han suratul fatiah Kan sinu opon ola bimo se ko sinu iwe yan a o wa fun gbogbo mim re loju tobaje wiipe afeki obinrin Kan nifewa a o fi aniyan wasi pelu oruko obinrin naa tobajewipe okunrin lafe koni fewa a o fi oruko okunrin naa si.. tobajewipe omo ise Kan lofe ki oga ohun nife ohun a o fi oruko oga re si pelu aniyan wa...a o wa ma mu pelu iyo ati oyin a o ma Han be lojojumo fun ojo meje kogbodo ja rara ooo...

Ona kej...ti aba need bibo asiri Kan tabi a need owo a o ma fi aniyan owo si nu gbogbo mim yan a o ma mu pelu iyo ati oyin pelu aniyan wa....a o ma Han bee lojojumo fun ojo meje kogbodo ja rara insahallah....
Koda ti obinrin basalo ale lo fun ki ama fi oruko re pelu aniyan pe kopada wasile...ti abale ko aniyan Yan ni larubawa alekoni Yoruba..

Iseyin daju pupo...olohun ajeki o jefunwa inshallah

07035001257 WhatsApp number

Alfa Muhammed onike ❤️

02/06/2026

Surah Al-Muddathir, Verse 12:
وَجَعَلْتُ لَهُ مَالًا مَّمْدُودًا 16,641

And give him vast riches

For any kind of HANTU print
WhatsApp number:08073699063
calling only:07085815530
Location ilorin kwara state

29/05/2026
25/05/2026

SARA HAYYU DAFIU FUN ASINA ISEGUN OTA TI ONA BADI YANYAN TIKOSI ONA ABAYO TESTED & COMFIRM

Aku imura odun tuntun olohun ajeki o bawa layo ati alafia...Ti onabadi mowa tikosi ona abayo funwa ti atije atimu balemowa tabi afebiya bukata Kan tabi afe ki olohun se nkankan funwa ejeki a gbinyaju asiri hayyu dafiu yin mi o mo bimose fe royin asiri but edakun ebami danwo....asiri hayyu dafiu po lodo eyin agbalagba ona po biwon se ma nlo ayyu dafiu lorisirisi lodo eyin agbalagba bi ise eniyan badaru tabi awon agbalagba bagbe owo le ogo eniyan tabi olowo olola niwa awon ota tida aye eniyan ru kosi iru isoro ohun hayyu dafiu ma yanjue..ejeki ki koko fi Sara yin kale naa...ona po timafi kale... inshallah...

A o din akara elepo ni adad kunfayakun ti se 71 tabi ki Ara lodo awon tiwon din akara ta but elepo logbodo je....a o wa toju a*o funfun opa Kan a o te silele a o wa se aluwala leyinna a o ya Nafilah meji leyin salamo a o se mukodimat leyinna a o wa daniyan Lori bukatawa a o wa Mamu akara Yan kookan a o ma ka hayyu dafiu kookan si Ara akara Yan leyokookan a o ma ju akara Yan sori a*o funfun opa Kan ti ate kale yan t**i yoo fi pe 71....( Ayyu dafiu 71 akara elepo 71) to aba ti kasi tan a o wa tun daniyan Lori isorowa a o wa fi akara Yan se sara fun awon eniyan but eniti o ni ise kogbodo je nibe oo...a*o funfun Yan a o loso sori akitan ni opari inshallah gbogbo nkan tabafi sori olohun magba bee ni...Ti a o balese adura yin fun arawa alebe Alfa taba trust kobawase adura yin pelu aniyan wa olohun agba adurawa..oyanju pupo..

07035001257 whatshap nomba

Alfa Muhammed onike ❤️

25/05/2026

https://www.facebook.com/share/r/1B7v3CDVvP/

You can watch the video on Facebook

Surah Al-Hajj, Verse 24:
وَهُدُوا إِلَى الطَّيِّبِ مِنَ الْقَوْلِ وَهُدُوا إِلَىٰ صِرَاطِ الْحَمِيدِ

Address

Tanke Bubu
Ilorin

Telephone

+2348073699063

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani:

Share