07/03/2026
OSE ITUWO
Ti awon Aye bawa ni Idi oro aye eda, nse ni eda yi o ma sise bi Alaikomose ni, opolopo eda lonse ise bi Erin Sugbon ti won nje ije Enliri, koda, gbese ti fe pa Elomiran latara pe Kori owo lati fi gbo awon bukata ti o ye.
Aisan ni won fi de (Tie) Elomiran mole lati bi Aimoye Odun, Elomiran ti na Aimoye owo ati awon Igbiyanju Miran lorisirisi Sugbon sibe sibe, eni na ko bo ninu idubule Aisan na t**i di oni yi.
Alakala (Bad Dream) ni ti Elomiran, ti o je wipe ojojumo Aye ni iwo fi nla awon Ala buruku yi, bi ki Egungun male Elomiran Kiri loju orun at bebelo, ti awon ala na si nihun se ninu Oro aye re.
Ti o ba gbiyanju ohun ti mofe ko o yi, o ma bo lowo aye patapa.
OHUN TI AOWA
Ewe Taba tutu 9 okunrin/7 Obinrin
Eso Werenjeje
Epo Obo
Ose Dudu
BI AOSESE
Ao gun ewe taba yi pelu Epo obo na dada TI yi o kuna, ao wa fi ose na ko, ao wa to Eso Werenjeje na yika Gbogbo ara Ose yi dada.
LILO RE
OKUNRIN yi o we ose yi fun ojo mesan
OBINRIN yi o we fun ojo meje
Ti a bati nwe ose yi Gbogbo awon eso Werenjeje na yi o ma Bo sile Lara ose na, Pelu ogo olohun Oba Gbogbo Ide aye eda yi o ma bere sini Bo sile ni.
Iwo na bawa share re fun Anfani awon Elomiran!
Mo gba Ladura pe ide aye Gbogbo ide ara wa yi o ja lase Eledumare 🙏🏾🙏🏾🙏🏾