07/07/2026
ÌMÙLẸ̀ ÀGBÀ
Olongbo dudu 1
ọ̀kùnrùn/ọ̀kùn 3
Iwọ́ran olokun 3
A*o waji dudu die,
Epo obo die,
Eru alamo die,
Odidi atare 1.
Ao koko pa olongbo yi ao ko gbogbo ifun inure kuro ao ko awon nkan toku yii sinure yatosi a*o
waji,
ao wa fi a*o waji dudu yi we daadaa,
ao tun fi owu dudu di.
ṣugbọn ki ato bere jijo ise yi agbodo ti
ra Akuko adie meji ati Abo adie kan sile,
Akuko kan lao koko paa ao wa fi eje re yika aro tia felo,
ao ma jo ise yii tia ba jotan ao lo kunna ao wa da sinu seere kan ao paa akuko adie keji si ara
seere yen, ao fi eje re ra seere na dada ao tun le iye adie namo ara seere naa, igba ti aba felo iseyi,
ao bu die nibe, ao teni odu IROSUN OSO, sinu awo funfun ao pe gbolohun re si ao ta adin si,ao la.
OFO RE
Ake roro 3x,
Ala roro 3x,
Okara 3x,
Agunmote 3x
Ake roro loruko tanpe Ogun 3x
Alaroro
loruko tanpe Sanponna 3x, Okara loruko tanpe awon Aje 3x,
Agunmote loruko tanpe Orunmila 3×.
Nijoti eyin mererin nti ikole orun bowa si ikole aiye, ori iroko agunregeje ni wonrin, alapa ngbapa,
olodan ngbodan, awo ekiri lefidi eru,
nigbati etu awon eru yi n, ogoji obe (knife) ni wonba nibe.
Ogun ko mewa,
Sanponna ko mewa,
Awon iyami Aje ko mewa, Orunmila naa ko
mewa.
Orunmila wabere lowo awon meteeta pe, tie bade ile aiye, kinni eo mafi awon obe yiise?,
ogun ni ohun yoo ma fi obe tohun kola fun omo araiye, sanponna ni ohun yio ma fi obe tohun ba
omo araiye ja ni, awon iya mi aje ni obe tawon, ise ibi ni awon yio ma fise.
Wonni eniti oba ti se,
obe yi ni awon yio fiti ona mo ti kofini rise mo laelae, alaboyun tin robi pelu inira lojo ikunle,
wonni ise obe yi ni,
agan ti kori omo gbejo,
won ni ise obe yi naani, won ni eni tio ya were ton sinwin,
ise obe yi naani, awon meteeta wa parapo, won beere lowo Orunmila pe toba dele aiye kinni yoo
ma fi obe owo tire se?, Orunmila ni ohun yio ma fi obe tohun gba eniyan sile ni, Orunmila ni eniti kobani ise lowo, obe tohun ni, ohun yio fi jeki oni ise lowo, nje alaisan ti kogbadun, obe yii ni ohun yio
fi jeki ogbadun, oni alaboyun tode ori ikunle ti kori omo bi, obe yi ni, yio firi omobi ni irorun.
Orunmila wabeere lowo awon meteeta pe, tie bade ile aiye, kinni eewo tie kogbodo je?, Ogun ni
ohun kiije okunrun, sanponna ni ohun kiije iworan olokun, awon iya mi ni awon kiije eepo obo,
beeni awon kogbodo je eru, eewo ni awon kogbodo fi a*o waji dudu digo, awon meteeta wa
panu po beere lowo Orunmila pe kinni eewo tire, Orunmila ni ohun kiije adin, Orunmila wa sofun
awon meteeta pe, tie bade ile aiye, enikeni tie ba tinba ja, ti ohun bati mu nkan eewo yin tie ko
gbodo je debe, kie si owo ibi yin kuro kiakia toripe oni tohun tidi omo ohun niyen. Emi lagbaja
omo lagbaja di omo Orunmila loni ooo, kie si owo ibi kuro larami, kinlowo, kinlola, kindi eniyan
Pataki lawujo. Ao se adura
ETUTURE
Ao mu adie abo yi, ao la laya ao ni ko ifun Inu re kuro ao gbe sinu awo ipese, ao bu die si ninu ebu
yen, ao fi epo pupa die si ao se opolopo adura si, pelu gbogbo ohun tia fe ati eyiti akofe, niihoho ao
wa gbe ipese yen losi eti odo lale ijo ti ase ise yii gangan
AKIYESI
Ao fi awon akuko adie mejeeji yi se saara ni eni toni ise yii kogbodo je nibe.