Bamdex herbal and spiritual issues

Bamdex herbal and spiritual issues https://wa.me/message/QAOXD5QIQLSBM1

we offer you natural herbs remedy for any health challenges 100%herbs and root very Effective
(14)

IWULO ATI ANFAANI OYIN IGAN ✅1.OGUN OJU ; Ti Oju re ba nse ipin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun...
19/03/2026

IWULO ATI ANFAANI OYIN IGAN

✅1.OGUN OJU ; Ti Oju re ba nse ipin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun po mo ara won. Maa kan si oju mejeji.

✅2. INU RIRUN ; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.

✅3. EGBO ; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.

✅4. EYIN OMODE ; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara won. Ki o si fun Omo na ni sibi kan lemeji lojumo lehin onje.

✅5. IKO IFEE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu Oyin Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo.

✅6. AIRI ORUN SUN; Maa mu Oyin Igan sun. Sibi meji lalale.

✅7. AILERA NINU OSU OBINRIN ; Nkan osu to nse segesege tabi to dudu (STOMACH PAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.

✅8 AROMOLEGUN ; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li ojojumo ni owuro kutukutu.

✅9 AKANDUN TABI EEWO(BOIL): Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.

✅10. OGBE INU (ULCER);Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to jeun aaro.

✅11. FUN ATO KIKI (SEMEN BOOST); Po eyin tutu po mo Oyin sibi marun. Lo gbogbo re leekan naa.

✅12. IKO EGBE ; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara won .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.

✅13. JEDIJEDI ; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro ati lale lojojumo.

✅14. ARUN ETI ; Ti eti ba nse oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po iyo die ati oyin mo ara won ma kan si eti mejeji laro ati lale.

✅15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.

✅16. ILE GBIGBONA ; Lo ewuro po mo Oyin Igan fi pa gbogbo ara, mu sibi mejimeji, lemeta lojumo.

✅17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO; Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta lojumo.

✅18. OMO TI O NTO SILE; Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji sun t**i tiko fi ni to sile mo.

✅19. IKO; Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin na bere si laa tabi ki o maa lo sibi kookan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.

✅20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara.

✅21.OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta loojumo.

✅22. ARUNSU ; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

✅23 .ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo.

✅24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.

✅25. EJE RIRU;Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.

✅26. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sisè kan oyin je.
✅27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo.

✅28. INU RIRUN ; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.

✅29. FUN ARA DIDAN ; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.

✅30. FUN IFA RUN AGBON: Po etu mo oyin igan ma fi pa.

✅31.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.

✅32. FUN ARAN; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.

✅33.KI INU OBIRIN GBONA:Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

✅34 FUN IBA REFUNREFUN; Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

✅35. BI INA BA JO ENIYAN;Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.

✅36. BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.

*✅37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etu imi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).

✅38. OGUN EJE; Omi osan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.

✅39. BI ARA BA UN GBONA: Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.

✅40. BI INU BA DUN OBIRIN;Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo.

✅41.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.

✅42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.

✅43. OGUN ATOSI: Omi jaganyin to po die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.

✅44.KI ENI TO BA NI ATOGBE; Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. O ma din sugar ku lara.

✅45.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.

✅46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki afi omi se haha agbado ki oma fi oyin igan mu bi tea ni aro ATI lale.

✅47 Ki agbalagba ma lo oyin lati mu tea tabi ogi ni ara ro ,o ma jeki opolo jipepe.

✅48 iwulo Oyin fun opolo omo akeko:
A o wa oyin gidi, omo akeko yio ma la sibi meta meta siwaju laro Toba koko ji ....

✅49 Eni ti ko ri orun sun: ko lo ra epo igi asufeyeje lodo awon alagbo,ko lo die Kuna po papo mo oyin. Ko ma la sibi meji lale .

Bamdex herbal and spiritual issues
07084932710
We Sell original honey

08/03/2026

If you're not ready for sacrifice or appeasement do not seek for divination or consultation

02/03/2026

Amin ase edumare

02/03/2026

Second video about egbe isn't a ritual

Our jedi flusher Tested and confirmed 👌
02/03/2026

Our jedi flusher
Tested and confirmed 👌

27/02/2026

Watch till end

26/02/2026

Learn from this 👇👇👇

26/02/2026

Claim this prayer 🙏
Amin ase edumare

20/02/2026

🦷 Stop suffering because of toothache o!
No remove your teeth when solution dey.
Order our Ose Akokoro (Toothache Soap) today!
✅ Tested
✅ Confirmed
✅ Works fast
DM now to get yours before price change.
5k only

Address

Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Bamdex herbal and spiritual issues posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Bamdex herbal and spiritual issues:

Share