Agbesinga agbaye

Agbesinga agbaye DR. AGBESINGA AGBAYE SPIRITUAL AND NATURAL HERBS REMEDIES
HERBS� DOCTORS, HEALTH MOTIVATIONAL, SPIRITUALISM, ISLAMIC LECTURE, MOTIVATIONAL SPEAKER. BLOGGER
(4)

AGBO TUTU IWĘ FUN AFUN. Ao ewe Ewuro ati ogiri-ijębu papo fi pa omo naa lara fun wakati kan ki ato fi ose-AFUN węę QSE-A...
25/08/2026

AGBO TUTU IWĘ FUN AFUN. Ao ewe Ewuro ati ogiri-ijębu papo fi pa omo naa lara fun wakati kan ki ato fi ose-AFUN węę

QSE-AFUNOMO. Aogun Ewe Abonię mo ose dudufiwę omode naa.

IRIN AJO ALA NINU AIYE OMO ENIYAN LAGBARA PUPO,, GBINYANJU LATIMO ITUNMO ALA RE1)Bi alala ba la alape won ta ohun loju a...
24/08/2026

IRIN AJO ALA NINU AIYE OMO ENIYAN LAGBARA PUPO,, GBINYANJU LATIMO ITUNMO ALA RE
1)Bi alala ba la alape won ta ohun loju ala tabi won npolowo re gegebi eru yoo ri aponle pelu lyi ateye, to ba jasi pe obinrin lo mpolowo re, tabi raa sughon to ba je pe okunrin lo raa O njasi ibanuje.

2)Kiko igbe eran sinu apo loju Ala
O ntoka si owo ati arisiki to po lodi won boba se po to

3)Titujuka ninu Ala
To ba jasi pe eni olohun lo ba larufe ala bee o ntoka si iduunu lori tolohun, to ba jasi pe cniti kii siniohun ni, o njasi didara po mo awon obileje eniyan.

4)Nini iye lapa ninu ala
O ntoka si jije oga ati riri oore.

5)Bíi obalala pe ilekún ilé re síi sile nii ojiji loju ala
Itumo:-sora fún fifi oro lọ ore ki won mase pada tu ee lasiri'

6)Bíi obalala pe won já ilekún ilere loju ala
Itumo:- awon tii igbokanle re wà lára won yóo tu ee lasiri'.

7)Bíi obalala pe osì ilekún fún arare loju ala
Itumo:- ona yóo la fún ee lojiji tera mo adua.

8)Bii obalala pe oun ta oja owa ún gba owó repete lójú ala
Itumo:- wa rii gbésè lori ise re tera mo adua.

ANU OLOHUN KI O GBA E LOWO EEGUN TI KII JE KI ENIYAN RI OUN RERE SE NINU AIYE,
BIJAHI KUNFAYYEKUN 🤲🏼🤲🏼🤲🏼

OSISE FUN ITUSILE,KOSI BI ONAA SE LE DI TO,TI ENYAN BA LO ASIRI YI ONA YO SI LA KEDERE,,SUGBON RI DAJU WIPE O OFI EMI IM...
24/08/2026

OSISE FUN ITUSILE,KOSI BI ONAA SE LE DI TO,TI ENYAN BA LO ASIRI YI ONA YO SI LA KEDERE,,SUGBON RI DAJU WIPE O OFI EMI IMORE HON KO DE PIN FUN ELO MIRAN KOLE JE ANFANI RE TO LE SISE FUN O DADA O
ewe ewuro tutu die,ao ko ewe ewuro yen sinu ike kan ..Ao gbo ewe ewuro yen dada,ao fi ase se idoti re, ao wa da sinu perfume 777 Ao fi kafura belebe meta si,ao gbadura si wipe ki ona wa la kedere,, koko pin asiri yi kosi fi adura fun wa tori fun afani awon elomi na ni,ao wa ma da diedie sinu omi iwe wa lararo,ti eyan ba lo asiri yi onitohun yo ma ri alanu...

HAAAA  ERINWO WON NI TAIWO HASSAN OGOGO OMOKULODO  PADA KU 😭😭😭😭😭😭😭 INALILAI WAINA ILAE ROJIHUNAAT LAST OGOGO IS GONE MAY...
23/08/2026

HAAAA ERINWO WON NI TAIWO HASSAN OGOGO OMOKULODO PADA KU 😭😭😭😭😭😭😭 INALILAI WAINA ILAE ROJIHUNA
AT LAST OGOGO IS GONE MAY ALLAH GRAN HIM JANATU FRIDAUZ😭😭😭😭😭😭

MA WULE DA ARA RE LAMU, TUNLO GBINYAJU ASIRI YI, ,MA JE KI WON TAN O JE, KOSI ENITI YO SE ASIRI YI TI KONI RI AYIPADA, T...
23/08/2026

MA WULE DA ARA RE LAMU, TUNLO GBINYAJU ASIRI YI, ,MA JE KI WON TAN O JE, KOSI ENITI YO SE ASIRI YI TI KONI RI AYIPADA, TI OLORUN BAFI ASE SI FUN OO,,TI A BA LO ASIRI YI AO RI OWO GIDI LARIN OJO META,, ENITI KO BA RI AYIPADA LEHIN ASIRI YI KI ONITOUN LO WE ORI RE SI OKUN OO,, TABI KOLO WA AFORIJI TOPO SIWAJU OLORUN..
to ba di ale,ti a ba fe sun ao mu agbon eyokan
okurin yo Fi agbon yen Kan iwaju Ori wa nigba mesan, obirin yo Fi agbon yen Kan iwaju Ori re nigba meje,ao wa so nkan ti a ba fe si,ao wa fi si igun yara wa mojumo ojo keji, ti o ba wa di aro kutukutu ao tu omi Inu agbon yen sinu omi toto wa we,ao ju agbon yen nu,ao wa fi iyo die si Inu omi ti a tu omi agbon yen si ati oyin original si ,ao wa Fi omi yen sanra lesekese, olorun afi alubarikasi yio bawa Lara mu ooo

O JE BOJU TO ORO ARA RE LONI,OJO NLO LORI RE O,BOYA IWO TI GBIYANJU T**I TI KOSI IYATO FUN O,BOYA IWO TI ROPIN WIPE KO SI ONAA ABAYO FUN O MO,

23/08/2026

AWON AISAN TO GBODO TETE MOJU TO

20/08/2026

KINI ANPE LOGUN/ BAWO LOGUN SE WO ILE YORUBA

OBA ALAFIA LOLORUN  YAH SALAM Olohun, dákun, fun gbogbo àwọn aláìsàn tó wà ní ilé ìwòsàn lalafia Tọ́pẹ́níyẹ. 🙏🏿🤲🏿Dákun, ...
19/08/2026

OBA ALAFIA LOLORUN YAH SALAM Olohun, dákun, fun gbogbo àwọn aláìsàn tó wà ní ilé ìwòsàn lalafia Tọ́pẹ́níyẹ. 🙏🏿🤲🏿
Dákun, má jẹ́ kí àìsàn tó burú bá wa ja. Fún gbogbo wa ní ìlera, àlàáfíà àti iwoṣán. Ameen. 🙏🏿❤️

PELU OGO OLORUN ASIRI YI ABA E LARA MU TEDA OBATIDURO YIO DE IBI TONLO LATI OJO TA TIN LO AJO ORISIRISI ONI GANGAN NI AD...
19/08/2026

PELU OGO OLORUN ASIRI YI ABA E LARA MU TEDA OBATIDURO YIO DE IBI TONLO
LATI OJO TA TIN LO AJO ORISIRISI ONI GANGAN NI ADURA WA O GBA , OLORUN MA TOBI OO, GBOGBO WA LAO RI OWO NAA LASIKO YI PELU OGO OLORUN , AJE INKAN TI AKO FOJU SI LE YI IGBESI AYE WA PADA SI RERE, igbale tafi gbale nikan la nilo, boya onise lowo tabi Iwo Koni ise kankan lowo mofi dayl loju wipe adura wa ti gba loni.. gbogbo irawo pata ni asiri yi ba sise, sungbon wa gbo mi loni oo ranti ojo ti yo ku Iwo ati eleda re ninu sare kosi ranti ese mefa ..Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ese mefa ( bi eyan ba se asiri yi ahhh Iwo sa lo ko date ojo yen sile tori oni gbabe Ojo yen si rere ninu aye re , kin lo je wipe ilu le,,,,ti o ba di ni aro kutu ,eja ka koko gbe omi gbona kanaa, ao wa da iyo die sinu omi gbonaa naa,,ao ni suru ti omi yen ma fi tutu die, ao wa mu igbale tafi gbale, ao duro Lori igbale na , ao wa se adura gbogbo inkan toba Fe si rere boya Lori ise re tabi Iwo nilo Owo tabi Iwo wa alanu ,Iwo sati se adura inkan toba fe Lori igbale ta duro le Lori yen,,ti o ba fe ko sise fun o koko coment ko de share re tori fun afani awon elomi na ni, leyin ti abati se Adura edun okan wa tan, ao ni kuro Lori igbale na ao wa fi omi yen ta da iyo si yen sanra lesekese, ti a ba ti fi omi yen sanra tan , ao wa da igbale yen pada sibi tati mu ,loba tan,,a le ma lo igbale yen pada,,ti a ba le se asiri yi Ahhhh hmmm adura wa ti gba niyen ooo,

Opolopo lo ti bo sowo scammer ori Facebook, o ti sun elomi nigbati kori onaa abayo,elomi o se ni igbagbo ninu alfa, pastor, babalawo mo,sugbon mo fi da o loju loni wipe maro arare pin ooo NIGBAGBO NINU OLORUN ATI NINU AYANMO RE WIPE KOGBODO SERERE LAIYE.. SO NI WAIYE ASAN OOO

SORA FUN AWON ISE ASIRI NLA NLA  TI OJO ORI RE OBATIWO 40---50 YEARS  TORI KOLEPE LAIYE NI OOO... SUGBON AWON ASIRI ADUR...
18/08/2026

SORA FUN AWON ISE ASIRI NLA NLA TI OJO ORI RE OBATIWO 40---50 YEARS TORI KOLEPE LAIYE NI OOO... SUGBON AWON ASIRI ADURA BAYI KOSI ENIKENI TIO LE LO
BOYA ASIRI TODAJU SI WA TABI KOSI,ASIRI ELEYI NI GBOGBO WA YO FI MO, ENITI O BA MO WIPE IPO TI OUN WA KO TE OUN LORUN,TETE LO GBIYANJU ASIRI YI NISIYI, SUGBON KOKO RI WIPE O COMMENT KO DE SHARE RE SI GROUP MARUN,,TI ENYAN BA SE ASIRI YI TI KO BA RI AYIPADA KI ONITOHUN LO WE ORI RE SI OKUN OO, ASIRI YI MA JE KI OGUN SE, ASIRI YI MA JE KI ONAA LA GIDI OO,,
Ao lo ra fanta eyokan,ao fi orogbo eyokan sinu fanta yen,ao wa fi iyo die si,ao wa gbe si iri mojumo ojo keji,to ba wa di aro kutukutu ojo keji ao pon omi toto wa we sinu bucket kan, ao wa,tu fanta yen si,okurin yo pe oruko re si ara orogbo yen nigba mesan, obirin yo pe oruko re si nigba meje ao wa fi orogbo yen nu gbogbo ara wa,ao so orogbo yen nu,ti o ba fe ko sise fun o koko coment ko de share re si group marun tori fun afani awon elomi na ni, ao wa fi omi inu bucket yen sanra,,ti ile ojo yen to su ao ri alanu,ati owo,sugbon share re si group marun ,to de coment to le sise fun o dada

Opolopo lo ti bo sowo scammer ori Facebook, o ti sun elomi nigbati kori onaa abayo,elomi o se ni igbagbo ninu alfa, pastor, babalawo mo,sugbon mo fi da o loju loni wipe mafi igbinyanju ati adura sile oo 🙏🙏🙏ilekun onaa aseyori re atosi fun oo

Address

Lagos

Telephone

+2348061677730

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Agbesinga agbaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share