Dr. agbesinga agbaye

Dr. agbesinga agbaye t. c
(1)

Health is wealth, tradomedical, herb 🌿 training, and any spiritual solutions, Prayers to solved any problem, Hontle( Arabic writup)
Airomobi, Aisan iju, any spiritual attacks,
e.

08/08/2026
ASIRI JUST OGUN LO  LOGBIYANJU ISE KEKERE YI WO.. MO BURA LONI FUN IWO TO BA NI GBAGBO WALAHI WA RI TI SE NINU DECEMBER ...
06/08/2026

ASIRI JUST OGUN LO LOGBIYANJU ISE KEKERE YI WO..
MO BURA LONI FUN IWO TO BA NI GBAGBO WALAHI WA RI TI SE NINU DECEMBER YI ,ONA TI WAFI RI TI SE RE OO , PELU IRORUN NI OO, LA DARA RE LAMU RARA ,WA RI OWO DEBI WIPE NINU OWO NI WA SODUN ,
fun gbogbo eyin tewa nilu oyibo ati kakiri aye te nilo Owo ni kiakai fun odun e sare lo se asiri yi , gbogbo irawo pata ni asiri yi ba sise oo... sungbon wa gbo mi loni oo ranti ojo ti yo ku Iwo ati e le da re ninu sare kosi ranti ese mefa ..Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ese mefa...(whalai mo bura Mafi oju di asiri yi, asiri yi yo tu aye opolopo eyan se gan oo ,beni yo mu yan ri opolopo Owo, , ao lo ra iyo alagolo ,aro kutu loda ka se ise yi, ao wa da iyo yen si ilele , ao wa gbe ese (leg) wa sori iyo yen ,ao wa ma gbadura si bayi wipe bi mose gbe ese mi Lori iyo yi loni gbogbo Ogun idewo idena to be ninu ara mi mofi iyo baje loni oo nitori wipe aditu laye di iyo, ki osu yi to pari ki ri temi se oo , ki Owo wa Mi ri oo, ni Tori taba Dami si ori ile lo bo , kiri batise ki ri ona gbe gba Amin . .,..

Koni sise fun o ti o ba ti comment ki o de share re oti di ase tori fun afani awon elomi na, leyin ti aba ti gbadura si tan, ao wa fi igbale gba iyo na da sita tabi kalo da iyo na danu ,bi eyan ba Dan asiri wo eru Olorun yoba onitohun oo pelu irorun ni ao ri owo tafi sodun pelu ogo Olorun,
FOLLOW ME FOR MORE....

MO TI SO FUN YI TELE WIPE ALFA TEMI YATO SI TI AWON POSI SORI FACEBOOK.....

05/08/2026

TANI OBAYEJE NINU ISLAM ATI ONISESE

AINI IFUNRA AWON  OKUNRIN  NIPA IBALOPOOKUNRIN PELU IBALOPO (MAN WITH S*X)Bofe boko kosi ona ti obinrin legba tofile bo ...
05/08/2026

AINI IFUNRA AWON OKUNRIN NIPA IBALOPO
OKUNRIN PELU IBALOPO (MAN WITH S*X)

Bofe boko kosi ona ti obinrin legba tofile bo lowo ibalopo lowo okunrin, nitori wipe ibalopo pelu okunrin da gegebi afiseni.

* Ti wọn ba fẹ ran ọ lọwọ, wọn yoo beere fun ibalopọ.

* Ti wọn ba sọ pe wọn nifẹ rẹ, ibalopọ ni wọn nfẹ.

* O ṣe aṣiṣe sun lo, wọnma fẹni ibalopo pelu re.
* Won fe ya owo lowo re, wonma feni ibalopo pelu re.

* Wọn fẹ fun ọ ni iṣẹ kan, wọnma fẹni ibalopo pelu re.

* Wọn fẹ lati fun ọ ni iwe-iwọle ninu awọn idanwo rẹ, wọnma fẹni ibalopo pelu re.

Alakọkọ, awon okunrin nilo ibalopo nigba kigba adamo awọn ọkunrin ni. Wonko sebu nitori wipe wọn ko ṣẹda ara wọn.

ṢIbadan.wipe 95% Ilera awon okunrin wa pẹlu okó 🥒 lile ni? Okunrin ti alafia bawa fun dada gbogbo igba ni oko re yio ma se ise sile,

Iyen lofi jasi wipe ti okunrin basun jiji ti okunrin bamaji won maji pelu oko won ni, nkan meji lolemu ki Oko okunrin mobaji pelu lile, alakoko ti okunrin ba nse are (sick) elekeji ti okunrin bani ibalopo lati oju orun, ti okunrin bamaji nigbana oko okunrin koniba ji ni lile.

Bí Ọlọ́hun ṣe dá wọn nìyẹn, Iyen lofi jasi wipe obinrin gbodo mafi ihoho re pamo nigbogbo igba, obinrin tobako latifi ihoho re pamo, iwakuwa koletan lawujo wa pelu isekuse,

Idi ni yii ti awon ijo gidi koki nfeje ki awon obinrin ti won ni a*o kukuru joko si iwaju lawujo tabi ninu Ile ijosin, nitori won yoo da ori awon asiwaju lokunrin wonru pelu ihoho arawon, Gegebi obinrin seni libido beni awon okunrin naseni tiwon besini libido ti okunrin nba oju won se iseni.

Lofi jasi wipe kosi ibikibi ti okunrin tiri obinrin arare koni bale, debi wipe ti okunrin bari aworan (picture) arewa obinrin oko 🥒 okunrin simale si lairi ri,

Anabi Yusuff (Joseph) ni ada ni eda alamumora nibi ibalopo sugbon sibesibe pakute obinrin mu, idiniyi ti Anabi Yisa (Jesus) se ṣọra gidigidi lati maṣe fi obinrin kan sinu awọn ọmọ-ẹhin rẹ.

Nitori wipe ọpọlọpọ awọn ọkunrin nlala loti ṣubu nitori ibalopọ. se o ro wipe wọn febẹ ni? ọpọlọpọ awọn ọmọ-ogun ni won pa nigba
ogun nitori obinrin kan ninu igbo.

Eleyi lose akoba fun Anabi Daud (Dáfídì) nipase Omo eyinre toran losi oju ogun kio tode o tigba iyawo re, Konilo lati sọ fun ọ nipa Samson alagbara?

Anabi Sulaimon (Sólómon) àtàwọn míran
Olohun nikan lofo arare mo nipa obinrin lati ara agbara re, Bí ara ọkùnrin ṣe máa ń ṣe sí ìfẹ́ ìbálòpọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ara obìnrin, melo ninu obinrin lofe ka nipa iwa ibalopo toleto ti okunrin?

Nitorina nigba miran ti ọkunrin kan baṣe aṣiṣe nitori ibalopọ, maṣe ri i bi ẹranko. iseda eran ara niyen. Iyen lofi jasi wipe nibi ibalopo ni opolopo obinrin ma ngba latimu tabi lu okunrin ni jibiti, ni awon okunrin nase ma nduro de obinrin nibi Iranlowo,

Beesini okunrin ti arare baku nibi ibalopo kosi ibiti obinrin tiferi mu beesini iru okunrin bee koni ni irori latini iyawo debiti yiori riran ri iyawo miran leyin iyawo ilere,

Beesini iru okunrin bee kole ni anu loju nitori wipe kosi nkanti o lemu anu obinrin wasi won lokan lara won,

Eleyini awon obinrin komo ti opolopo obinrin sema nfi oju olojukokoro wo gbogbo okunrin tabi eniti ojure kogbe ibikan, okunrin tikoba ni alafia topeye iru won ni koki nni oju koro obinrin, beesini kosi obinrin tole feran okunrin tikoda pe, ewoni obinrin fefi owo mu?

Mosoyi moduro fun Ibere tabi itoni sona lori oro igbesi aye ara eni.
CALL 📞 OR WHATSAPP 08061677730

04/08/2026

ORO OLOLU PT2

MADA ORO MI NU KOLE NI IFOKANBALE       EWA NIKAN KO    {Is not only beauty}AWON NKAN TOMA N MU IFE OBINRIN DINKU LOKAN ...
04/08/2026

MADA ORO MI NU KOLE NI IFOKANBALE
EWA NIKAN KO {Is not only beauty}

AWON NKAN TOMA N MU IFE OBINRIN DINKU LOKAN OKUNRIN{Those things make man loose interest in woman}

Igbagbo awon obinrin kan nipe ewa nikan ni ohun ti okunrin nwa lara obinrin, Bi olorun bawa jaja se won ni arewa obinrin, won awa fima se igberage si okunrin.
Bi eba wo inu aye loni, pupo ninu awon obinrin ti won o si nile oko, yala ti won ti kuro nile oko, tabi ti won o ti e tiwo ile oko rara, Awon arewa obinrin na poju ninu won, Ohun tosi fa nipe opo ninu won lojepe ewa tan ni gan lo nse akoba fun aye won.
Awon miran n ri ewa won bi ohun ti awon lefi se igberaga si okunrin, tori ero okan won nipe gbogbo okunrin na nifesi arewa obinrin, Beeni, kosi okunrin ti o nifesi ki obinrin rewa, Sugbon nje eje mope bi obinrin base alaini awon nkan timo feso yi, Botiwu kiru obinrin be ni ewa to, oma pada di oburewa loju okunrin ni
Ife nimu ki okunrin riran ri ewa ara obinrin, Obinrin ti awa okunrin ba nife, arewa niru obinrin be loju wa, Sugbon toba tile dipe ife n dinku lokan okunrin, arewa obinrin ama pada di oburewa loju okunrin.

Kani ewa nini nafi n gbe ile oko ni, awon obinrin kan wa to daju pe won o ni kuro nile oko won dojo ale, nibi tan ni ewa de, Sugbon ewa nini koni obinrin fi n gbe ile oko, Aimoye awon arewa obinrin nita, ti won o si nile oko, Aini iwa gidi lo n koba awon miran, Ara rire pe mi o lefe lagbaja lo n koba awon miran, nitori ewa tan ni, Olowo nimo fefe lo n koba awon miran, Igberaga ewa lo nse awon miran, ti opo won fi n pada kuro nile oko won, ti awon miran o seti ri ile oko wo.
Bosi sewu ki obinrin ni ewa to, ewa n pada bo wa felo lara

BI OBA NSE AWON NKAN YI, IFE RE LEMA DINKU LOKAN OKO RE TABI LOKAN OKUNRIN TO NFE.

1)Bi oba je obinrin toma n gbo oko re lenu Bi iwo ati oko re bajo ni gbolohun a*o, ohun re ma nlo soke ju ti e lo, nise ni wama pariwo le lori, Oki fun loro so rara, Bi iru iwa bai ba n tesiwaju be, olefa ki ife re ma dinku lokan oko re.

2) Bi oba je obinrin tiki gboro si okunrin to nfe lenu, to n ri niri pe kole ma pase fun e, tinu re ni wa se, Biru iwa yi ba n te siwaju be, olefa ki ife re ma dinku lokan okunrin na.

3) Bi obaje obinrin tiko ni ifarada, omo asiko opo si asiko oda, gbogbo igba toba ti n bere nkan lowo okunrin to nfe, kosa ma fun e ni, Bi o ba ri nkan na fun e, Ija bere niyen, Biru iwa bai ba n te siwaju, olefa ki ife re ma dinku lokan okunrin.

4) Bi oba je obinrin tiki gbo, tiki gba, ibinu ni, ni gbogbo igba, oro kekere ti o to nkan, wati sodi ibinu, Bi iru iwa yi ba n tesiwaju, olese okunfa ki ife re ma dinku lokan okunrin to nfe.

5) Bi obaje obinrin tiki dana ounje ni asiko fun oko re, oko re o de feran koma jeun ni ita, iru nkan bai lemu ki ife re ma dinku lokan re, nigba toba sososo, ti o si iyi pada.

6) Bi obaje iyawo ti o ki pon awon ebi oko re le, oki se dada si awon ebi oko re, kosi okunrin ti inu re ma n dun siru nkan be, ole muki ife re ma dinku lokan oko re.

7)Bi obaje iyawo toma nko ibalopo fun oko re lopo igba, toki fe gba ki oko re ba e se ere ife, Bosi gba gan, oni jeki oko re se gbadun, Iru nkan bai na lemu ki ife re ma dinku lokan oko re.

8) Bi obaje obun obinrin, toki tun ile se debi toma tun ara se, iru nkan be lefa ki ife re ma dinku lokan oko re.

9) Bi obaje onijangbon obinrin, ti wahala ki su, gbogbo igba ija ni, ole muki ife re ma dinku lokan oko re.

Die niyi kara awon nkan tole muki ife obinrin ma dinku lokan okunrin
Bi oba je arewa obinrin, sugbon toku die kato si awon nkan timo so yi, tobaya ewa re o ni pada niyi loju okunrin mo, Ewa nikan ko nimu ki okunrin nife eni o, o gbodo ni iwa gidi pelu re
Lotito ife lo n gbe igbeyawo ro t**i lai, Sugbon bi awon akude kan ba n sele ninu igbeyawo, olese akoba fun ife, ti ife asi ma yinrin die die, t**i tofi ma yinrin tan
Ninu awon ohun timo ka sile yi, awon kokan nawa nibe toba okunrin na wi, tojepe bi okunrin na ba nse, olese okunfa ki ife re ma dinku lokan iyawo re na
Ju gbogbo re lo, eje ka mojuto igbeyawo wa, tori enikeni ti igbeyawo kan bati ipase re tuka, iru eni tu odidi ilu kan ni, yosi kesan re lodo olorun oba

Fun marriage counseling
Fun s*x counceling larin tokotaya tabi awon tan sese fefe ara won
Marriage counseling fun awon afesona meji
Ipari ija larin oloolufe meji
Bi oba nwa oko abi oun wa aya
Bi oba ni arun kan lara ti ofe se itoju, Ma tiju lati bami so awon nkan timo ka sile yi, kosi eni ti o ni ti e lara, Eda toba n fi eda egbe re se yeye ninu isoro re, eso fun iru eni be pe didirin ni, tori boba joko, to ronu nipa oro aye ti e na, Isoro ti e gan leju ti eni tofi nse yeye lo, sugbon koni riran ri ti e, teni eleni lo mama ri.
Bi oba fese family planing to comfirm, tosi je alalope, ti o ni aleebu kankan to nse fun ara
Eyikeyi toba nfe ninu awon nkan yi, Iwo sati bami soro ni WhatsApp tàbí kope mi,,,,,,,,

03/08/2026

WASILAT VS OLOLU IBADAN PT1

03/08/2026

CONFIRMED AND TESTIMONY LORI ILE AKOPATI

Address

Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Dr. agbesinga agbaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Dr. agbesinga agbaye:

Shortcuts

Share