ILERA Adayeba Naturals

Directions

ILERA Adayeba Naturals 🌿 Ìmọ̀ Ìlera ní Èdè Yorùbá
🩺 Natural Wellness & Healthy Living
🍲 Health Tips • Recipes • Myth vs Fact
❤️ Kọ́ ẹ̀kọ́. Mọ̀ òtítọ́. Tọ́jú ara rẹ

17/09/2026

ILERA KO BERE NIGBA TI A BA SAISAN N'KAN.

16/09/2026

Healthy lifestyle kise Ounje nikan ...Je ki a ko bi a sele maa toju ara wa ni ona to peye .
‎
‎ #

14/09/2026

ARA WA NILO OMI LATI MAA SISE DAADA ...
MA SE MA DURO T**I TI OUNGBE YOO FI PO GAN KI O TO RANTI OMI .



02/09/2026

‎📢
‎“Ti o bá fẹ́ mọ àwọn àmì pàtàkì tí obìnrin kò yẹ kí ó foju kọ́, tẹ̀lé ILERA Adayeba, kí o sì share video yìí fún ob ìnrin míì.”

31/08/2026

Kí í ṣe gbogbo ìrora ara ni malaria ń fà. 🦟❌

‎“Follow ILERA Adayeba fún àwọn ìmọ̀ ìlera tó rọrùn, tó sì wúlò fún ìgbésí ayé ojoojúmọ́.”
‎

26/08/2026

Portion + Variety + Preparation = Important.

🌿 Ìlera Adayeba — ìmọ̀ ìlera ní èdè Yorùbá.
Èwo ni o fẹ́ kí n sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ next—EWÀ, Ẹ̀FỌ́ tàbí ẸJA? Kọ ọ́ sí comment 👇🏽 Diet Eating

25/08/2026

Tí o bá fẹ́ mọ àwọn ohun tí aboyún yẹ kí ó máa ṣe ní gbogbo trimester, follow Ìlera Adayeba, kí o sì comment ‘ANC’.”
‎
# ILERAAdayeba # ANC # Antenatal # PregnancyTips # Yoruba Health

20/08/2026

🌿 Ìlera Adayeba — a ń pín ìmọ̀ tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti bójú tó ìlera rẹ.
Ṣé o ti ṣàyẹ̀wò BP rẹ̀ lọ́sẹ̀ yìí? Kọ “BẸẸNI” tàbí “RÁRÁ” sí comment. 👇🏽



# Health Tips

19/08/2026

Tí o bá fẹ́ mọ̀ síi nípa bí o ṣe lè máa bójú tó ìlera rẹ, follow Ìlera Adayeba, kí o sì comment 1, 2 tàbí 3—èwo ni o máa ń ṣe dáadáa jù?”

# Natural
# Wellness
# Healthy Living
‎

17/08/2026

KÍ LÓ DÉ TÍ ARA RẸ FI Ń MÁA RẸ̀WẸ̀SÌ NÍ ÌGBÀ? 🤔 # Ileraadayeba

Address

Abeokuta Way
Ibafo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ILERA Adayeba Naturals posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share