Peace Home Traditional & Herbal Healings Centre

Peace Home Traditional & Herbal Healings Centre Our traditional medicine is good for comfortability of life both physical & spiritualism .

13/06/2026

Not every closed doors are locked •
Push to confirm , it's only needs your energy •
Alfa Taofik cares •
08106069403 !!! •

13/06/2026

Idunun ati ayo a wole gbogbo wa.

Awon agan a towo ala bosun.
🙏❤
Alfa Taofik cares

Bí ìṣẹ́ bá ń ṣẹ́ ọ̀dọ́ ní àṣẹ́jù, kó lọ sí igbó erin; bó bá pa erin, ìṣẹ́ rẹ̀ á tán; bí erin bá paá, ìṣẹ́ rẹ̀ á tán.
09/06/2026

Bí ìṣẹ́ bá ń ṣẹ́ ọ̀dọ́ ní àṣẹ́jù, kó lọ sí igbó erin; bó bá pa erin, ìṣẹ́ rẹ̀ á tán; bí erin bá paá, ìṣẹ́ rẹ̀ á tán.

07/06/2026
07/06/2026
{ AGAN ~~ BARRENNESS }Agan nii Yoruba n p*e nii Obinrin tii koo-i-tii-ri Omo bii . Oogun tii a n fun won nii , a n p*e n...
06/06/2026

{ AGAN ~~ BARRENNESS }

Agan nii Yoruba n p*e nii Obinrin tii koo-i-tii-ri Omo bii . Oogun tii a n fun won nii , a n p*e nii ( ALAAGAN ) .

FEMALE INFERTILITY [ AIROMOBI ] .

Ohun tii o lee faa nii awon Arun bii ;

1 - Iju .
2 - Ase Oyan
3 - Ase dudu
4 - Ase Lii-laa-mi
5 - Akan-ru
6 - Akan Inu
7 - Eeda Oro Ati Idubule
8 - Ato Sisan
9 - Oju Ara Obinrin yiyun
10 - Ise Owo Omo eniyan
11 - Oolo Inu
12 - Atosi Oolojo pii-pe Inu Ara .

ATI bee bee loo .

Okunrin naa nii tiire Laara pelu tii o n faa Aa-i-rii-omobi .

Agboo-gi wa fun Okunrin Ati Obinrin naa fun Ona abaayo .

1 . Agbo tii ohun eelo eeroja ibile tiwa n tiwa ree jee Meewa p*ere ati Ooru tuntun . Oko pelu Aaya nii won o maa mu .

2 . Omi Agbon toopo , Eeso Abeere , pelu ohun eelo eeroja 4 p*ere . Mimu die die lehin Ojo Karun tii a tii ree .

3 . Eran Eelede die , Eepa-kun , Baara , Omo-nii-geele-geele , pelu ohun eelo eeroja 5 . Ooru tuntun , tí a fii Ako Okuta merin tee-le ikooko Oru naa . Kiini a fii see ? . Idi ree o gbodo kan-le , koo-si gbodo ru paa-na . Mimu nii Aaro tii Oyun yio fii-de .

4 . Afaara ibooju Oju Igbin toopo , Owo eyo 7 , pelu ohun eelo eeroja 2 p*ere . A o loo kunna . O nii Ona tii Obinrin naa yio gba loo .

5 . Egbo Asunwon egba , pelu Ewe jii-ja meji p*ere , Ata Aaso-feiye-jee , Iru wooro , Iyo , Eepo . Aseeje nii eyi , kiini nii a fii pelu ree see-je ? .

Agunmu ree pelu Ose ree naa waa too daaju bee .

We can as well , cut fruit of Kigelia Africana , Allium Ascalonicum with 3 leafs & 1 ingredient to it . We boil it & drink decoction .

Beeni , Olohun loo n fun eniyan loomo , Kii see eniyan .

Pelu Ogo Olohun , Awon Agan a biimo yee " Aameen 🕋🙏 " .

IWOSAN see pataki loori Arun Inu Aago Ara omo-nii-yan .

E jee kaa too-ju Ara wa pelu Ewe jii-ja ati Egbo wii-wa , ibile tiwa n tiwa .

Herbs for life confirmed .

Alfa Taofik cares @ Oyo Alaafin township .

06/06/2026

My heart goes out to everyone going through what they cannot discuss with anyone. I pray GOD will see you through.
🙏🏻

29/05/2026

We parents & our children will never be a victim of ra**st, ritualist & kidnappers by God grace • Happy Friday
ALFA TAOFIK CARES

Address

Agba Akin Compound ~ Agunpopo , Oyo Township
Oyo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Peace Home Traditional & Herbal Healings Centre posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Peace Home Traditional & Herbal Healings Centre:

Share