Baba Alado

Baba Alado I'm Dr Olanrewaju Power (Baba Alado) Which Treat in Traditional African ways

Ose ituwo ati ebu asina owo kiakiaMoki gbogbo olorire to wa ninu yara alalubarika yi wipe ao ni fi osi logba o ise asino...
20/08/2026

Ose ituwo ati ebu asina owo kiakia

Moki gbogbo olorire to wa ninu yara alalubarika yi wipe ao ni fi osi logba o ise asino yi daju pupo sugbon olohun oba daju ju lo aimoye eniyon ni owo awon agba ti wa ni ara re ti awon ise to nlo kofi be dahun lara re mon elo mi nbe oti we ose oti je aseje sugbon ti kori iyato nbe ti iru eni be si ni awon olorire ti won le sanu fun legbe sugbon ti won ko ri tie ro owa sise bi Erin o wa nje ije elirii elo bami gbiyonju ise yi wo bayi bayi

(1) alubasa
(2) odidi atare
(3) owo eyo
(4) iru pete
(5) foto wa
(5) itano ewe rerinkomi

Bayi ni ao ti se ise yi :-- ao wa alubosa ti anfi nse obe to tobi dada kon ao wa pa ni pansa lori ao fi owo eyo ti koluju kon si ao wa fi ideri re de pada ao wa mun iru Pete yen ao son mon gbogbo ara alubosa yen ti ibikonkon koni hon lara alubosa yen mon ao wa foto wa kon tia daya fun arawa ao fi tele inu agbada ao si oju re soke ao wa gbe alubosa yen le lori ao fi odidi atare nla kon si legbe ao wa da itona ewe rerinkomi le lori ti awon nkon to wa ni isale inu agbada yen koni hon mon ao wa jo won papo ao lo ti yio kuna dada ao wa bu die ninu ebu yen ao gun po mon ose dudu tabi ose gana omin agbon ni ama fi de ose yen ao gun ti yio mun dada ao ko sinu a*o funfun ao wa gbe si inu ike funfun olomori kon ao de ao ma bu we larolaro

ao ma lo ebu yen pelu shinap eni ti ko ba le lo hot kio ma fi oyin tabi ogere epo pupa lo ebu naa laro ati ale kio to sun pelu. Ase olohun oba iwo ti olohun oba bani kio ri ise yi se wa dupe lowo olohun oba lase edumare

Ebami share re:--
Ebami like re ;--
Kie si ma follow mi;--

Nitori ki awon elomi naa le je anfani ose asina yi alanu wa yio fi anu wa wa ri oo amin ๐Ÿ™

20/08/2026

I got over 1,700 reactions on my posts last week! Thanks everyone for your support! ๐ŸŽ‰

Ebu eyonu imule awon agbalagba todajuKia gbiyonju lati ma lo eyonu imule awon agbalagba dada nitori pe gbogbo eni to ba ...
19/08/2026

Ebu eyonu imule awon agbalagba todaju

Kia gbiyonju lati ma lo eyonu imule awon agbalagba dada nitori pe gbogbo eni to ba saba ma nlo eyonu tabi eni ti imunle awon agbalagba ba wa ni ara re kosi gbogbo ibi ti eni naa le de ti ko ni mo ri anu gba tabi kosi gbogbo ibi ti eni naa bade ti won o ti ni ma ni ife re lati ma se ni anu eni ti imunle awon agbalagba ba tun wa wa ni ara re aiye ki tete ri iru eni be se ni ika tabi janba elo gbiyonju re wo kie wa dupe lowo olohun oba

(1) ori olongbo tutu
(2) eso laa pupa gbigbe
(3) odidi atare nla
(4) ewe Papa*on tutu
(5) ewe sawerepepe
(6) ewe rerinkomi tutu

Bayi ni ao ti se ise yi ;-- ao wa ori ologbo to ti nse ode ri dada (1) eso laa pupa gbigbe pelu odidi atare nla meta (3) ati ewe Papa*on tutu ewe sawerepepe tutu pelu ewe rerinkomi tutu ao ko ewe Papa*on yi tele inu agbada ao wa gbe ori olongbo yen le mon le ao wa to odidi atare nla metata yen yipo ori olongbo yen ao wa ko eso laa pupa yen lewon lori ao wa ko ewe sawerepepe si ewe rerinkomi ni ao ko lewon monle gbeyin ao wa gbe kano ao jo won po dada ao wa lo ti yio kuna ao bu die ninu ebu yi ao gun lose pelu epo obo ao fi epo pupa de ose yen ti yio mun dada ao ko si inu ike funfun olomori kon ao de pa

Ojo ti aba bere si ni we ose yi naa ni ao bere si ni lo ebu yi sugbon kia ri wipe anwe ose yi dada ti aba we ose yi ton kia to ma jade lo ao bu die ninu ebu yi laro ao fi fo eko tutu mun tio ba di ni ale ao da sinu ogere epo pupa ao ma la kia to sun

Ema bami share re:--
Ema bami like re :--
Kie si ma follow mi ;--

Nitori ki awon elomi naa ki won le je anfani ose ati ebu yi anu olohun oba koni kuro larawa lase edumare amin aseee

Ose ki oko legun tabi kio tobi dadaFun anfani awa okunrin to je wipe inkon omo okunrin wa kere ju ojo ori wa lo boya abi...
18/08/2026

Ose ki oko legun tabi kio tobi dada

Fun anfani awa okunrin to je wipe inkon omo okunrin wa kere ju ojo ori wa lo boya abi mon ni tie ni tabi aison kon lo fa ti nkon omokunrin naa fi kere tori awon nkon mi wa to le fa ki inkon omokunrin kio kere ju ojo ori lo eleyi ti mun ki iyawo ile ati oko re tuka latari wipe kori nkon to nfe lodo oko re mon sugbon ose yi dara pupo to si ma nje ki inkon omokunrin kio gun siwaju ti yio si tobi dada fun iwo omokunrin ti inkon omokunrin re kere ju ojo ori re lo ti olohun oba bani kio ri ose yi se wa dupe lowo olohun oba gbiyonju re wo ti inu iyawo re yio si ma dun ni gbogbo igba to bati nri e

(1) pandoro nla
(2) ose dudu
(3) ogede agbagba nla
(4) epo atare nla

Bayi ni ao se se ise yi :-- eje kia lowa pandoro kon tio gun tosi tobi dada pelu ogede agbagba kon to gun tosi tobi dada pelu epo atare nla kon to tobi dada eje kia mun pandoro yen kia fi obe ge ori re pelu idid re sinu odo eje kia gun kio kuna dada pelu ogede agbagba yen eje kia fi olo lo epo atare yen kio kuna dada kia wa dasi kia wa gun won papo mon ose dudu ejekia ri daju wipe ose dudu ni alo kise ose funfun yen o eje kia gun kio mun dada kia wa kosi inu ike olomori kon kia de pa

Lilo re :-- okunrin naa yio ma bu diedie ninu ose yi laro tio ba ti we ton yio fi omi si yio ma fi wo nkon omokunrin re si iwaju kogbodo wo si eyin o tio ba tun fe sun ni ale naa yio tun bu die ninu ose yi yio fi omi die si yio tun fi wo nkon omokunrin re si iwaju pelu ase olohun oba kio nigba ti yio fi lo ose kon iyato yio ti de ba nkon omokunrin re

Akiyesi :-- ti okunrin na bati lo ose yi to ri wipe inkon omokunrin ohun ti jade si dede bo se fe kio ma lo ose naa mon oooo

Ebami share re;--
Ebami like re :--
Kie si ma follow mi :--

Nitori ki awon okunrin min naa ki won le je anfani ose yi alafia wa koni di fiafia lase olohun oba

Ose itaja to daju Moki gbogbo eyin olori ire towa ninu ile  alayo yi wipe ao ni fi osi lo igba laiye wa o eleyi ni ose i...
15/08/2026

Ose itaja to daju

Moki gbogbo eyin olori ire towa ninu ile alayo yi wipe ao ni fi osi lo igba laiye wa o eleyi ni ose itaja to daju sugbon olohun oba daju ju lo gbogbo iwo to je onisowo tabi iwo karakata tabi iwo tio je wipe osi shop kale lati aro kosi eni to nba e ra oja tabi iwo tio ro wipe agbano ti wo inu ogun aiye re tabi iwo to nri owo to je wipe o mon bi owo naa nse pora mon e lowo elo bami gbiyonju ose yi wo

(1) ewe olosepetu
(2) ewe lapalapa pupa
(3) ewe efinrin oojo
(4) itano ewe rerinkomi oojo
(5) ataijosi
(6) epo obo

Bayi ni ao se se ise yi ;-- eje kia wa ewe olosepetu pelu ewe lapalapa pupa ati ewe efinrin oojo itanao ewe rerinkomi oojo pelu atajosi (9) fun okunrin meje fun obinrin (7) pelu epo obo die eje kia gun won papo dada kia wa da ose dudu tabi ose to ba wuwa le lori kia wa gun dada eje kia fi omi agbon tia fo fun ara wa po kio mun dada kia wa ko si inu ike olomori kon kia de pa fun ojo meta leyin ojo keta eje kia ma bu we laro laro

Akiyesi ;-- gbogbo igba ti aba we ose yi ton ema je kia fi a*o nu ara wa eje ki aje ki omin yen kio gbe mon wa lara kia wa fi ipara to ba wuwa pa ara wa kia ma losi idi ojo wa tabi ibi ise wa pelu ase olohun oba iyato yio de ba inu aiye eni ti olohun oba ba ni kio ri ise yi se lase olohun oba

Iwo naa ba mi share re
Iwo naa bami like re
Iwo naa bami comment

Nitori ki awon elomi naa ki won o le je anfani to wa ninu ise yi asiri wa koni tu lase olohun oba

14/08/2026

Ogun fun oyun iju (Fibroid)Eegbo se lo to ni wipe kosi itoju fun arun oyun iju itoju to pe ye wa fun dada ni tori wipe a...
14/08/2026

Ogun fun oyun iju (Fibroid)

Eegbo se lo to ni wipe kosi itoju fun arun oyun iju itoju to pe ye wa fun dada ni tori wipe arun yi kise wipe inkon to sese nse yon ni arun to ti wa lati odun to ti pe ni sugbon olohun oba nlo ewe ati egbo fi toju arun yi nitori wipe ewe ati egbo ni awa babanla wa nlo ti ewe ati egbo naa si wa t**i di oni ti ale fi toju arun oyun iju yi ti yio si kuro lara eni naa

(1) epo igi iroko
(2) konhun alabere
(3) epo oson orornbo

Bayi ni ao ti se ise yi :-- epo igi iroko pelu konhun alabere ati epo oson orornbo ao wa ko won si inu ikoko ijogun ao jo won papo dada ao lo ti yio kuna dada ao ro si ibikon obinrin naa yio ma lo

Lilo re ;-- gbogbo eni ti arun oyun iju ba nda lamu kio bu sibi kon ninu ebu yi kio bu omi oronbo sibi marun si kio gbe mun kio ma. Mun ni ekon lojumon sugbon gbogbo eni to ba ni arun osa ko ma se lo ise yio ooo

Ebami share re ;--
Ebami like re ;--
Kie si ma follow mi :--

Nitori ki awon elo mi naa ki won le je anfani ise yi olohun oba koni fi aison se wa ooo

Ose ti anfi nwe /epe /asasi/abilu/eegun idile/eron ikorira/ kuro ninu ara Aimoye ona ni aiye ama fi binu eni ti won ba t...
12/08/2026

Ose ti anfi nwe /epe /asasi/abilu/eegun idile/eron ikorira/ kuro ninu ara

Aimoye ona ni aiye ama fi binu eni ti won ba ti ri wipe ologo omo ni ti won yio si fa owo ogo naa si eyin fun beni ni Aimoye eni to je wipe epe tabi eegun idile ni ko je kio ri ogo re lo besi ni Aimoye eni to je wipe ohun lo fi owo ara re fa ogo ara re seyin nibi aiko mon iwa wu tabi aiko mon oro so loti fi enu ara re fa ogo ara re seyin mofe kie mon wipe ibi ti ide wa be naa ni tude wa bi oro ose yi se ri ni yen fun iwo ti olohun oba bani kio ri ise yi se

(1) ewe lapalapa pupa
(2) ewe lapalapa funfun
(3) epo obo
(4) iyo isebe
(5) ewe sinkinrinmindin
(6) sugar onikoro
(7) lofinda onala

Bayi ni ao sese ise yi ;-- eje kia lo wa ewe lapalapa funfun eyo meson fun okunrin eyo meje fun obinrin kia wa ewe lapalapa pupa meson fun okunrin meje fun obinrin epo obo die ewe sinkinrinmindin sugar onikoro eyo meta iyo isebe die pelu lofinda onala ao gun awon ewe meteta yi lodo pelu epo pelu sugar onikoro eyo meta ao wa da ose dudu le won lori ao gun won po dada ao wa da iyo isebe die si eyin atelewo wa osi ao wa so bayi pe

Gblohun re :--- ao da iyo die si atelewo wa osi ao wa te iyo naa ni odu ejiogbe ao wa so wipe oju owo ni won di ona mon enikon kidi ona mon eyin owo gbogbo aburu to ba wa lara emi lagbaja omo lagbaja leni ejiogbe wa lo gbe fo kuro lara mi aditu ni won ma di iyo loja omo araiye ni tu gbogbo egun idile/epe /abilu/asasi/eron ikorira/ ati awon nkon aburu mi to ba wa lara emi lagbaja kio bere si ni tu kuro lara mi lati oni lo

Awo wa da iyo naa le ori ose yen ao tu lofinda onala si ao wa gun ose yen ti yio mun dada ao wa ko si inu ike olomori kon ao de pa ao ma fi ose naa we larolaro fun odidi ojo meje gbako leyin ojo keje ose naa kowulo mon oooo elo mi kosi le lo ninu ose yen ooo

Bami share re ;--
Bami like re ;--
Kie si ma follow mi ;--

Nitori ki awon elo naa ki won le je anfani to wa ninu ose yi anu olohun koni fi gbogbo sile ooo amin

12/08/2026

I got over 850 reactions on my posts last week! Thanks everyone for your support! ๐ŸŽ‰

Osole eyonu imule awon agbalagba ti won fi ti olore eni si ni kiakia Mo ki gbogbo eyin olorire tie wa ni inu yara alalub...
11/08/2026

Osole eyonu imule awon agbalagba ti won fi ti olore eni si ni kiakia

Mo ki gbogbo eyin olorire tie wa ni inu yara alalubarika yi wipe gbogbo wa ao ni fi osi lo igba lase olohun oba owu mi lati fi osole yi ta gbogbo wa lore tori awon ti won ti lo won si ndupe lowo olohun oba bayi bayi osole yi wulo ninu aiye omo eda ti o si ma tete mun ki eni ti ati ko wipe yio se ni lore kio tete sawa ri eni lati se ore yen fun eni naa kiakia

(1) ori olongbo
(2) ewe ajeobale
(3) ewe sawerepepe
(4) odidid atare
(5) ewe ola

Bayi ni ao ti se ise yi ;-- eje kia wa ori ologbo kon to ti nse ode ri dada koje tutu ewe ajeobale oojo ewe ati itona sawerepepe tutu oojo ewe ola ekun owo kon pelu odidi atare nla meta ao fi odidi atare meta yen se aro ninu agba ijogun yen ao wa gbe ori olongbo yen le atare yen ao wa da ewe ola ekun owo kon le won mon le ao wa ko ewe sawerepepe tutu yen lewon mon le ati ewe ajeobale ao wa jo won papo

Akiyesi ;-- ti aba njo ise yen lowo ao wa hot lord igo kon ao ma ta ideri kokon si inu ise yi t**i yio fi jo ton tio ba wa jo ton ao so ao wa lo ti yio kuna dada ao ro si inu igo funfun kon ao ma wa lo diedie

Lilo re ;--- gbogbo eni ti olohun oba ba ni kio ri ise yi se mo fe kio ki ara re ku ori ire ti e ba fe lo ise yi ona meji ni ao ma gba lo ise yi

Ti aba fe lo laro kututu ao ma fi hot lo tabi oyin tabi omi lasaon sugbon tio badi ale ao ma fi fo eko tutu mun ni kia to sun pelu ase olohun oba ise yi yio ti alanu ti yio se o lanu nla sie ni kiakia lase edumare

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Baba Alado posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share